Home / Àṣà Oòduà / Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.

Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.

Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù .
Àwòrán tí ó gbòde yí ni ó yà ní èbá òkun ní ìlú Èkó. Toke tí won so wípé bí ó bá yá ti è yóo ju ti Kim Kardashian lo.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.