Home / Àṣà Oòduà / Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia

Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia


Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia.  Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo meji sodo. Musa naa gba goolu kan wole ninu ifesewonse to waye lopin ose yii eleyii to mu apapo boolu to gba wole je mefa ninu liigi oreede Russia.

Orisun

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo