Home / Àṣà Oòduà / Maheeda di Pasito oloro itunnu

Maheeda di Pasito oloro itunnu

Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n mu inu awon ololufe re dun.

About oodua

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*