Home / Àṣà Oòduà / Osa Esu

Osa Esu

Osalogbe Awo Apala
Osalogbe Awo Apalaa
Adifafun Orunmila Ajana
Baba Yoofi Oro jagbajagb’a ro Sorun Esu
Babagbebo
Babarubo
Esu Odara ti n ba Ni Owo lowo Odorun re Esu Odara Odorun re
Esu Odara ti n bani Aya Odorun re Esu Odara Odorun re
Ti n ba bimo
Ti n ba Ko ile
Esuodara ti n ba ni Esin
EsuOdara ti n ba Ni Ire Gbogbo Odorun re
EsuOdara Odorun re
Rudurudukee
Adifafun Orunmila Ajana lojo ti Ire Gbogbo n’lo lojude Edu ti Okookan koyale wa
Babagbebo
Babarubo
Rudurudukee Akara kan Soso Nimoyan fun Esu Ire Aje waa Yale tomi wa o O
Rudurudu Kee Ifakan kii tomi Sol’a
Akara kan Soso Nimoyan f’esu
Ire Aya
Ire Omo
Ire ilekiko
Ire Esin
Ire Alaafia
Akara kan soso nimoyan f’esu Nire Gbogbo Yale tomi wa ooO Rudurudu kee Ifakan kii tomi Sol’a O
Osa Esu✍
Osa n jagbe laja
Awo Baale Difafun Baale won ni kora Ori re legba Nitori Iku
Ogbebo
Orubo
Eetiku ooO
Adesee Akangigiri kii ku ooO
Adesee Akan Gigirii
Igimemu
Igimemu
Igi Alaworo Agutan ni n mondun Memumemu
Adifafun Orunmila Baba Yiowa Igunre mon Esu Odara lorun
EsuOdara darere wa ooO
Dare Sasa darere waa fun Awo ??
Osa Esu✍
ESU ODARA YIOGBE WA O?
HAPPY WORLD ESUODARA DAY ✋

About asatiwa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Yoruba Esu & European Satan: What a generational Colloquial misconceptions !

Satan is an European language and it’s best interpreted by the same European people. Conceptually, in Yoruba culture, ESU and Satan remains different in meaning and does not mean the same. While Satan relates to wickedness of people, Yoruba ESU provide reliefs to people! The knowledge acquired on Yoruba ESU deity revealed that Esu do provides, protects, guides and offer blessings to Yoruba people….that’s why there were many ancestral Yoruba names like ESUGBURE, ESUGBOHUN, ESUDARE, ESUNIGBAGBE, ESUYEMI, ESUFARE…..etc Esu belonged ...