Home / Àṣà Oòduà / Radio Biafra Ti Pada Senu Ise: Se Kii Se Wi Pe Awon Omo Yibo Fe Da Ogun Biafra Mi-in Sile?

Radio Biafra Ti Pada Senu Ise: Se Kii Se Wi Pe Awon Omo Yibo Fe Da Ogun Biafra Mi-in Sile?

Radio Biafra
Ile ise Radio Biafra ti ikanni re je 104.7 FM eleyii ti won bere si gbe ohun safefe lai gbase, ti ijoba si ti siwon lowo ise ninu osu keje tun ti pada gbe ara otun mi-in wo bayii. 

Ko to di wi pe won ka apa ile ise Radio awon omo yibo naa lowo ko, Ipinle Enugun ni owoja re kari; sugbon loteyii, kaakiri ile yibo lo dabi eni wi pe won ti n gbo ile ise radio naa.

Ile ise radio Biafra yii ni enikeni ko le so ibudo kan pato ti ile ise naa wa. Pupo ninu awon ohun ti won si n gbe safefe naa lonii se pelu awon oro ti n lo lowo kaakiri ile Nigeria. 

Ohun kan to daju nipa ile ise radio yii ni wi pe won ko niwe ase; bakan naa ni enikeni ko mo ibudo won ni pato. 

Awon onwoye si salaye wi pe o le je lara ona ati igbaradi awon omo Yibo lati pin gege bi a se ri igbiyanju won lodun 1967 eleyii to sokunfa ogun abele.

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*