Home / Author Archives: Awo (page 37)

Author Archives: Awo

Àwon akékòó ilé-èkó gíga Calabar is ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò .

   Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).

Read More »

Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

    Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ...

Read More »

Gbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.

Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.

Read More »

Jamil Balogun, omo Tiwa Savage yo pèlú àrà òtò nínú àwòrán tí ó yà.

   Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.

Read More »

Buhari ti búra fún Boss Mustapha gégé bíi akòwé ìjoba gbogboogbò (SGF).

    Àare Muhammadu Buhari ti se ìbúra fún akòwé ìjoba gbogboogbò tuntun tí ó n jé Boss Mustapha . Ayeye ìbúra náà wáyé ní yàrá ìgbìmò Ààre.

Read More »

Olópàá tí owó tè nígbà tí ó n gba owó èyin ní ojà Yola.

    Gégé bí ò n lò èro ayélujára tí ó gbé ní Yola tí ó pín ìròyìn ìsèlè yí se so, olópàá tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí ní won yà nígbà tí ó n GBA owó èyin ...

Read More »

Terry G se ayeye ojó ìbí fún omokùnrin rè, Teerex nígbà tí ó pé odún márùn-ún.

   Omokùnrin Terry G, Teerex pé omo odún Márùn-ún bàbá rè sì se ayeye ojó ìbí náà fun pèlú àwon òrò tí ó dùn tí ó pín sí orí èro ayélujára (Instagram).

Read More »

Cossy Orjiakor ní ilé-ìwòsàn tí ó fé se isé abe kí ìdí rè le yo.

    Cossy Orjiakor tí a mò wípé óní àyà ni a ti gbó tí ó ti kérora nípa ìdí rè tí ó kéré lénu ojó meta yí, sùbón báyìí ó ti lo sí ilé-ìwòsàn láti sisé abe kí ìdí ...

Read More »

Ìyàwó ga oko kúrú.

    Àwòrán àwon tokotaya tuntun, kí olórun fún won ní adùn ìgbéyàwó . Èyí ò wa rewà bí…

Read More »

Patoranking lo kí Timaya pèlú okò rè tuntun tí won n pè ní Porsche.

Gégé bí Timaya se pin sí orí èro ayélujára(Instagram) tí ó sì wípé . ” omo mi ti dé pèlú àrà òtò, gbogbo ìgbà ni ó ma n mú orí mi wú. PATORANKING mo féràn re ….

Read More »