Home / Àṣà Oòduà / Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

    Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ìdí látàrí ó kò láti wo inú èwon.

About Awo

One comment

  1. Oye Kiwon Ran Olopa Yen Lo Si Ewon Ni.
    Iwa radarada Ni ogbeni Yii wu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?