Home / Àṣà Oòduà / Oríkì Obàtálá

Oríkì Obàtálá

Ọbàtálá ọbátárìsà
Ọba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjé
Ọba nílé Ifọ́n
Ò sùn nínú àlà
Ò jí nínú àlà
Ò tí inú àlà dìde
Òrìṣà wun mi ní budo
Ibi Ire l’òrìsá kalẹ

Akú òsè Obàtálá O

About ayangalu

x

Check Also

Obàtálá

Obàtálá (Ìwà) Amúyan abìtanná yanranyanran Adia’fun orunmila babá o tanná fórìsà riwa Ebo lawo ni kose Ógbébo órúbo Ógbèrù ótèrù Njé ifá tan sílé, èdú tan sónà Tan ni o mòpé ina ire lope ntan Bàbá arúgbó that: Sleeps in purity Rise in purity The great craftman that mould eminence into human beings The most purity that dwell in white #Oturupon_rosun Òrìsà májekí ìwà mi o bàjé…Àsē o -Awo