Home / Oṣelu (page 2)

Oṣelu

Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò Náà Rẹ́ – Fayemi

Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi ...

Read More »

Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́

Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ìgbésẹ̀ òhun ìhùwàsí oníkálùkù láàyè, ìtàn ló ń kọ lóké eèpẹ̀.Tẹbi tara tọ̀rẹ̀ àti àwọn èèkan nísẹ́ Ìjọba ló péjú láti ṣé ajọyọ̀ ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bí ọdún karundinlọgọrin ...

Read More »

615″, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀

“615”, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ wọn ni oju bayii ni alakan fii sọri.Eyi naa lo mu gomina ipinlẹ Oyo,Ṣeyi Makinde gbe igbesẹ akin, ni bi o ṣe kede ńọ́ń́bà Ẹẹfa, ookan, ...

Read More »

Amosun se ileri ipe ofe ori foonu fun awon osise lodun 2016

Ijoba ipinle Ogun, labe akoso Senator Ibikunle Amosun, ti se ileri ipe ori foonu ofe fun gbogbo awon osise ipinle naa lodun tuntun 2016 to wole de yii.  Igbese tuntun yii ni olori eka imo ero ati ibanisoro, Ogbeni Olatundun ...

Read More »

“Oju Mimiko ni PDP yoo fi poora nipinle Ondo” – Oloye egbe APC

Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...

Read More »

Aregbesola ya ₦130m lati ko ile iwe girama kan

Iroyin Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Gomina Rauf Aregbesola tipinle Osun ti lo si ileewe girama, Olufi Middle School to kale si Gbongan ni Ijoba Ibile Ayedaade to wa nipinle naa. Nibi ayeye ti won ti n si ileewe naa ni ...

Read More »

Oselu Kogi: “Idi ti a ko fi yan Faleke ni yii” – Alaga APC

Alaga fun egbe oselu APC lapapo, Oloye John Odigie-Oyegun ti salaye idi pataki ti awon agba egbe naa fi pamopo lati yan Alhaji Yahaya Bello gege bi oludije ti yoo ropo Abubakar Audu, eni to jade laye saaju ki eto ...

Read More »

Emi ati Alao-Akala ti lepo di okan soso- Gomina Ajimobi

*Ajimobi fogbon juko oro si Ladoja Leyin awuyewuye ati awon oro ti n lo nigboro nipa wi pe gomina tele fun ipinle Oyo, Christopher Alao-Akala n mura lati darapo mo egbe APC ti pada jade lenu Akala funra re bayii. ...

Read More »

Akasu oro Fayose: “Eni ba fori so mi, yoo fo yangayanga”

Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose, ti fi da gbogbo ara ilu loju wi pe didun losan yoo so fun egbe alaburada, PDP, ninu eto idibo alaga ibile eleyii ti yoo waye lojo kokandinlogun osu kejila odun yii (19-12-15). Sugbon ...

Read More »

Oselu ipinle Oyo: Alao Akala ti wa ogbon mii da

Christopher Alao Akala ti wa ogbon mii da Nibayii ti Christopher Alao-Akala, eni odun marunlelogota (65) ti pinnu lati darapo mo egbe APC lati inu egbe Labour Party ni awon awuyewuye kan ti bere si ni jeyo jade. Lara awon ...

Read More »