Home / Uncategorized

Uncategorized

Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi

Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ ...

Read More »

Ilé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létí

Ejo ti ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja da ni ojo ketala, osu yii ni egbe oselu APC ni awon ko fara mo.

Read More »

Nnkan méje ti yóò yipada àti meje ti kò ni yi pada lẹ́yìn ti ilẹ Gẹ̀ẹ́si ti kuro labẹ EU

Lẹ́yin ọdún mẹ́ta lílọ bibọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Brexit, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì padà kúrò lábẹ́ EU ní aago mọ́kànlá alẹ́ ọjọ́ Jimọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kínní ọdún 2020.

Read More »

Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’

Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn obìnrin láti bá kọ́mú ...

Read More »