Home / Àṣà Oòduà / Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti
Yinka Alabi
Idaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se de ori ile naa.


Ijoba ipinle naa ni ki awon eniyan ilu naa maa lo ni irowo ati irose, won ni ko si ‘ewu loko,afi giri aparo’.
Ijoba ipinle naa ni ki won ma se beru rara. Ki oloko ma lo si oko re bee si ni ki olodo naa maa lo odo re, nitori pe ijoba ipinle naa ko ni laju re sile ki iya maa je awon ara ilu to n se ijoba le lori.
Awon ara ilu naa ni eru n ba awon nitori alakatakiti ni awon Fulani darandaran. Won ni kii gbo ki gba eda ni won.

About ayangalu