Home / Àṣà Oòduà / Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi

Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi

Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà.

Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ní kíákíá kí ò sì dá gbogbo owó àláwánsì tí ó gbà fún Àádòrún  ojó padà.

Nígbà tí ó sì wà ní ipò, ilé ejó gíga ti kéde Shuaibu Lau gégé bí asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà ti àríwá Taraba. Àse náà kún fún ìdájó tí ó wà nínú fáìlì ilé-ejó kò témi lórùn láti owó Shuaibu Lau, ó ta ko ìpinnu ilé-ejó kò té mi lórùn nígbà tí ó jáwé olúborí tí won sì gbe fún elòmíràn ní ònà tí kò tó.

Ile ejó tún pàse fún ètò ìdìbò (INEC) láti se ìwé-èrí tuntun fún ìpadàbò Lau.

Ilé-ejó gíga jù tó ri to ìpinnu àwon omo egbé tóronú márùn-ún tí ó wáyé wípé “olugbèjà ara rè ní ètó láti kópa gégé bi àwon tó kùn náà se létòó ní ìbèrè ó rò wípé wón yan òun je ni .ó ní ètó láti lo sí ilé-ejó .

Eni tí won fi ró pò rè ní ìbèrè pèpè ti ìbò rè se òfò nígbà tí ó jé wípé olugbèjà ara rè ló gbégbá orókè nínú ìdìbò náà. Ohun tí ó kùn ni wípé kí won kéde wípé olugbèjà ara rè ló gbégbá orókè ní ìbèrè pèpè.. …

Continue after the page break for English translation.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo