Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) léyìn àìsàn kékeré tí ó se é nígbà tí ó n sin ìjoba ní Makurdi ní ìpínlè Borno. Won ti sin-ín láàná ní ìpínlè River. Kí olúwa te sí aféfé rere.
Home / Àṣà Oòduà / Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.
Tagged with: Àṣà Yorùbá