Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú.
Ará ilé àti lára àwon tí ó figa gbága ní BBNaija rí ni Bisola Aiyeola jé tí àwon tí ó mò ó sì mò wípé ó ti bímo súgbón kàyééfì ñlá ni ó jé nígbá tí a gbó wípé ó kú, kí olúwa báwa te sí aféfé rere.
Sún re ooo.
Home / Àṣà Oòduà / Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú.
Tagged with: Àṣà Yorùbá