Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè.
Gégé bí ìwé ìròyìn Punch se so, Miracle jé omo bíbí ilú Agenenbode ní Etsako ìjóba ìbílè ìwó oòrùn ti ìpínlè náà, ta omo rè sí ilé àwon omo òrukàn fún élegbérún lónà igba náírà (#200,000) .
Miracle so wípé won ti òhun ni láti ta omo náà nítorí àìlówó lówó, àìrí nkan je .
Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.
Tagged with: Àṣà Yorùbá