Home / Àṣà Oòduà / ‎ITUMỌ Olowo

‎ITUMỌ Olowo

 

Alaye: Ọpọlọpọ eniyan ro pe gbogbo awọn ti o wa ni ipo nlanla bii: gomina, aarẹ, alaga kansu,…tabi awọn to n gun ọkọ nlanla tabi to n gbe’le nlanla nikan ni ‪#‎olowo‬ laimọ wipe ko ri bẹ rara.
‪#‎ITUMỌ‬: Itumọ olowo ni gbogbo eniyan ti asiri ẹ bo, to jẹ pe t’oba fẹ lo owo kan to n ri lo lasiko to yẹ ati asiko to fẹ.
‪#‎ẸKỌ‬: Ẹ ma jẹki a maa fi ọla awọn kan ta o mọ ibiti wọn ti r’owo wọn tọrọ mọ. Ni agbara Ọlọrun, asiri gbogbo wa koni tu, amin!!!

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*