Okò tí ó kó kírètì Coca Cola ni ó dànù ní òpópónà 3rd mainland bridge yí ó sì wó òpò kírètì àti ìgò ní orí afárá náà. Okò náà tún kolu okò kan tí a mò sí Toyota Corolla kí ó tó di wipe ó wó.
Yóò dára bí e bá le gba ònà míràn fún àsìkò díè, kí won fi palè ojú ònà yí mó.
Home / Àṣà Oòduà / Àkolùkogbà selè léyìn tí okò tí ó kó kírètì Coca cola dànù tí ìgò sì fó ní 3rd mainland bridge.
Tagged with: Àṣà Yorùbá