Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí rè ri…
Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí rè ri…
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...