Home / Àṣà Oòduà / Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tó yááyì.

Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tó yááyì.

John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò.
Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won fi se ayeye ojó ìbí won.

Òkan lára àwon ìbeta yí ni ó pin sí orí instagiramu tí orúko rè ń jé @jamietriplet, tí ó pín àwòrán náà tí ó sì ko ibi tí won ti baabò.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...