Home / Àṣà Oòduà / Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn

Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn

Á fi èpè fún elépè

Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè 
Àsẹ

Eu oro para que qualquer inimigo planeje o mal para mim e você será recompensado com o mal instantaneamente e lá cairá sobre eles pela graça de Deus
Um homem

Awóyemí Ọlọ́run wà 1

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo