Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.
Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì n je lénu, Yemi Alade àti Flavour náà ti se ti won tí won pè ni “Ìfé ya wèrè ( Crazy love).
Yemi Alade pín àwòrán ijó níbi tí ó ti n rèdí fún flavour sí orí èro ayélujára. Ó n jó ó sì tún rèdí.
Àwon ìlúmòóká bíi Chioma Chukwuka-Akpotha, Juliet Ibrahim, Toke Makinwa, Falz àti àwon míran sòrò.
Home / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.
Tagged with: Àṣà Yorùbá