Home / Àṣà Oòduà / Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ó má bá oko olóko sún kiri, tí ó sì jé wípé àwon kìlò fun tó, ohun tí ó máa n so ni wípé sebí ayé òun ni, àti wípé ohun tí ó ba wu òhun ni òhun le fi ayé òhun se, kò kan eni kéni.
Ó ti wá kan èèyàn báyìí oooo, kí á ya sóra.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo