Home / Àṣà Oòduà / Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye

Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye

Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. Sugbon igbagbo mi mbe ni Akogun ode orun.

Jagunjagun ti kii roju ogun ko to segun. Oba mi erujeje ti n lo niwaju to tun un bo leyin.

Iba ni i ma se lojo gbogbo.

Mo wa dupe lowo awon eniyan ti won ka iroyin wa losan-an loru, awon onibara wa ati awon eniyan ti won fe wa kari aye.

Olayemi Olatilewa Oniroyin dupe. Odun ayo ni gbogbo yoo se.

Alekun owo, omo, ayo, alaafia ati igbega. Ase

E ku odun!

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*