Àwon òsìsé tí ó ranilówó láti orílè èdè Denmark àti olùdásílè ètò ìsàkóso àwon èwe (Children’s Aid Education and Development Foundation (ACAEDF), Anja Ringgren lovên, ti ran omobìnrin odún méwàá lówó, omo tí a mò sí Deborah, èyí tí àwon ebí rè fi sílè fún ikú ní òpópónà . omobìnrin yí ni a gbô wípé ó ma bèrè ilé-èkó rè ní òsè tí ó n bò kí á dúpé lówó Anja Rimggren Lovên.
Home / Àṣà Oòduà / Omobìnrin kan ní ilè Akwa Ibom ni àwon ebí rè ti fi sílè fún ikú sùgbón olùrànlówó kan ti gbà á kalé.
Tagged with: Àṣà Yorùbá