Home / Àṣà Oòduà / Wón pa ológun Nàìjíríà kan ní Sambisa lónìí.

Wón pa ológun Nàìjíríà kan ní Sambisa lónìí.

Gégé bí olùrànlówó oníròyìn ti ìjoba ìpínlè Sokoto, Imam Imam òsìsé ológun (army officer) M Maiwada àwòrán eni tí ó wà lókè tí ó sèsè di Balogun (captain) ni won yín ìbon pa ní ojú ogun pèlú àwon Boko Haram lónìí ojó kejìdínlógbòn osù keje….

 

Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...