Home / Àṣà Oòduà / A kú osù tuntun oo.

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó
Esè la fí ñ rìnnà Olà
Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo…

Asáré pajé
Arìngbèrè polà
Òhun ewà ní wón jó n wòlú
Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn kàn
Tó re inú ìrókò lo ree múlé si
Tó n polówó ajé tantantan.
Ó ní Alájé eni kìí la, kínú ó bínii
Ñjé kí là ñ jé lótù Ifè tájé fi n yale ëni?
Ògèdè òmìnì là ñ jé lótù Ifè tájé fi nyale eni ..

Lónìí tí osù tuntun bèrè, Ajé yó fi ilé gbogbo wa se ibùgbé ooo… Àse..

ooduarere kí i yín, wípé a kú osú tuntun Ooo.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo