Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.
Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...