Oba Lamidi Adeyemi III, Alaafin tilu Oyo gbalejo Oba (Dr.) Adekunle Aromolaran, Owa tilu Ilesa ni aafin tilu Oyo
Alaafin ti bere ayeye odun marunlelogoji (45) lori oye pelu idije ese kikan niluu London Olayemi Olatilewa Oba (Dr) Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III ti bere ajoyo ayeye odun marunlelogoji (45) to gori ite awon baba nla baba re lode Oyo. Ayeye yii to ti bere lojo kinni osu kejila odun yii niluu London, nigba ti asekagba re yoo maa waye laafin Oba Lamidi lojo kerinla osu kini odun to n bo nibi ti awon oba alaye kaakiri ile kaaaro-o-ji-i-re ...