Home / Àṣà Oòduà / Àràbà Aworeni Adisa Makoranwale sun re.

Àràbà Aworeni Adisa Makoranwale sun re.

òní tí ó jé ojó kokànlá osù kejo odún 2018 (11/8/2018) ni ètò ìgbé òkú baba wa tí ó sísè ní ojo ìségun tí ó jé ojó kokànlél’ógbòn osú keje odún tí a wà (31/7/2018) sí isà .

Ìjo International Council for Ifa Religion (ICIR)pèlú àjo àwon láràbàláràbà ni ó se agbáterù ètò yí.

Atèwònràn ni èto yíì yóò ti wáyé.

Adisa Aworeni se béè ó lo, Kí ifá té baba sí aféfé rere. .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...