Home / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán obìnrin òyìnbó yí níbi tí ó ti kúnlè tí ó n fún oko rè lómi mú láti se ètó ìgbéyàwó ìbílè won. Won sì fi ìdùnnú jó.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...