Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.
Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò.
Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí kò wá máa se èyà tirè lóótò? Tí kò le d ilé isè tirè náà sílè.
