Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

   Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ó sì yi padà sí kìrìsìténì.

Àwon kan takò ó wípé báwo ni ó se ma yí padà nígbà tí kìí se wípé kò ní èsùn télè.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára