Home / Àṣà Oòduà / Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó. 

Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó. 

  Arákùnrin kan ní orílè èdè Nàìjíríà tí a mò sí Jefferson Uwoghiren, se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Edo. Arákùnrin náà tí kò so ohun tí ó fé fi eranko afayàfà náà se, ni a rí tí ó ya àwòrán tí ó de òni náà ní enu bí ó se ya àwòrán ojó-ìbí pèlú omo rè obìnrin àti àwon ebí t’ókùn.
Nígbà tí ó pín àwòrán náà sí orí aféfé, arákùnrin náà ko pé, “so ohun tí ó le selè sí òni yí, lóòní tí Omobìrin mi ń se ayeye ojó-ìbí rè……

Continue after the page break for English version

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo