Home / Àṣà Oòduà / Àwon Akékòó Ogbà Fémi jà fún ètó won

Àwon Akékòó Ogbà Fémi jà fún ètó won

Bí a bá pè é ní ìjà láàrin akékòó eka èkó gèésì (Department of English ) àti ti àwon eka èkó nípa òfin (faculty of law) ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university wo ìyá ìjàkadì Látàrí wípé àwon kan kò jé kí àwon kan wo yàrá ìkàwé.

Gégé bí a ti gbo, àwon law ti parí isé ti won tí Ó sì ye kí won jáde fún àwon English láti jé kí won w’olé, sùgbón tí àwon law kò láti yára jáde nígbà tí Ó jé wípé olùkó àwon English sì ti de láti kó won, Lóòtó èyí ló fa ìjà.

Ìjà yí kì bá tí selè tí ó bá jé wípé àwon alákóso ogbà ti pèsè àyè tí Ó tó fún awon akékòó láti kékòó.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo