Home / Àṣà Oòduà / Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ti mú, tí won sì ti tì wón mó àgó olóòpá tí ó wà ní Moore .

Ó máa wà nínú àkosílè wípé ní ojó kàrún osù kewàá odún 2017 (5/10/2017) ni àwon akékòó se àtakò àláfíà látàrí ohun èlò tí kò sí ní inú Ogbà. Ní ojó kejì àtakò yí, àwon ìgbìmò ìdábòbò ilé-èkó yí sáré lo sí ààrin àwon akékòó yí tí won sì mú méwàá nínú won, tí igbákejì ààre akékòó ifáfitì yí “Jacob Tosin(Emerald)”sì wà láàrin won…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo