Home / Àṣà Oòduà / Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .

Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì (45) ni àwon fúlàní tí won pa tí òpò sì fi ara pa .
Òkú àwon tí ó kú ti wà ní Mósúárì tí ó wà ní Numan tí àwon tí ó fi ara pa sì wà ní ilé-ìwòsàn.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...