Home / Àṣà Oòduà / Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).

Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).

Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó ìbí rè ní àrà òtò, nígbà tí ó fi àwòrán tí ó dára jowá lójú, tí ó sì fi yàwá lénu púpò.
Àwon àwòrán náa rewà púpò jù, e wò ní ìsàlè.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo