Olóògbé Arábìnrin Amaka Ezeokoli tí ó kú ní òsè mélòó séyìn léyìn àìsàn péréte , se ni won ti sin-ín ní ojó Àbáméta (Saturday) ní ìlú tí won bi sí ní Ezioko ní ìjoba ìbílè Gúúsù ti Orumba tí ó jé akékòó jáde ti eka èkó “Library and Information science” ní ilé-èkó gíga ifáfitì Nnamdi Azikwe (UNIZIK).
Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán ìsìnkú Akékòó jáde ti ilé èkó gíga Nnamdi Azkiwe (UNIZIK) tí ó kú ní òsè mélòó séyìn.
Tagged with: Àṣà Yorùbá