Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.
Olúwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tí ó jé Engineer ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Arábìnrin yí sì rewà púpò.
Àwòrán náà wojú rí.
Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.
Tagged with: Àṣà Yorùbá