Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá won sùn.

Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá won sùn.

    Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon omobìnrin Chinese tí won so wípé ó n bá sùn…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...