Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti wípé àwon ìlú ló ma dìbò fún won.
Gómìnà náà ní ti lo kí Alaafin ti Oyo Oba (Dr.) Lamidi Adeyemi keta, ní Oyo fún ìjókòò àwon ìgbìmò asòfin egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.
Home / Àṣà Oòduà / Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.
Tagged with: Àṣà Yorùbá