Gégé bí ìròyìn se so, won ti fi ìgò gún omo odún mókàndínlógún (19) yánmayànma látàrí àwon èyà ara tí won bá ní owó rè, won bá omoníka àti ojú ara omo odún mérin okùnrin ní Awka, ìpínlè Anambra.
Afura sí náà, tí a mò sí Ògbéni Sunday Onwebenyi láti Emeziaka Mgbo ní ìjoba ìbíle Ohaukwu ní Ìpínlè Ebonyi, tí ó jéwó wípé òun pa omo náà pèlú àwon afura sí míràn ní ibì kan nàà.
Èyí selè nígbà tí òré bìnrin láti agbègbè kan náà tí n jé, omidan Blessing Eze, ni ó ti so fún kí ó lo sí àdúgbò kan ní ìlú Awka, níbi tí owó ti tè é, èróngbà won ni láti tún rí owó púpò si.
Won ti fáà fún àwon olópàá fún Ìwàdìí tí ó tó.
Tagged with: Àṣà Yorùbá