Ò n lò èro ayélujára (Facebook) Bucandy Ayo Abubakar, tí ó jé onísé abe pín àwòrán ara rè àti bàbá rè àti bàbá rè onísé abe ti se isé-abe fún aláìsàn kan tí ó ní àìsàn “Appendix” ó sì ko síbè wípé .
“Nígbà tí bàbá re bá jé onísé abe ti ìwo náà sì jé ìgbákejì rè”.
Omo Àjànàkú kò le yàrá omo tí eyá bá bí eyá ní jo.
Home / Àṣà Oòduà / Àwon onísé abe; bàbá kan ní orílé èdè Nàíjíríà àti omo rè obìnrin ti se isé abe lórí aláìsàn won .
Tagged with: Àṣà Yorùbá