Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.

Àwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.

   Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán tí ìyá rè pín sí orí èro ayélujára.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...