Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom Kuti .

Mo gbàgbó wípé òrò ilé-ejó ni àwon akoni yí nso, àbí béè kó ni.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára