Home / Àṣà Oòduà / Awon foto: Ayeye Igbeyawo Omo Gomina Abiola Ajimobi Le Ku!

Awon foto: Ayeye Igbeyawo Omo Gomina Abiola Ajimobi Le Ku!

Oni ojo kokanlelogun, osu kejo (Aug 21), odun 2015 ni Gomina Abiola Ajimobi n se igbeyawo fun omo re obirin, Ajibola pelu oko omo re, Ayokunle Olayiwola.

Orisirisi awon eniyan nlanla ati awon gomina lati apa iwo-oorun guusu Naijeria ni won ti pejupese sibe. Omo Baba Olowo, Davido ati Olamide ko si dake orin lati maa fi da awon eniyan lara ya.

Afikun iroyin si n bo laipe…

orisun

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára