Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.
O ku die ko je gomina niku mu lo. Igba ti okiki re bere si ni i kan, lo wole sun. Ojo ti idile re i ba fo fayo, ni won bo sinu ibanuje nla. Ile aye asan, ile aye omulemofo. Bawo ni ko ba se dun to kiku gbowo? Sebi opolopo owo dollar ni won o ba ko le iku lowo. Sugbon iku o gbowo, Omooba Abubarka Audu niku mu lo. Rere run! Nnkan yan-an! Adura kan ni mo ...