Home / Àṣà Oòduà / Àwon fúlàní darandaran kolu àwon àgbè oníresì (Rice farmer) ní ìjoba ìpínlè Benue.

Àwon fúlàní darandaran kolu àwon àgbè oníresì (Rice farmer) ní ìjoba ìpínlè Benue.

  –Tí ó sì dá àpá sí  won l’ára.
Nígbà tí a wà lénu síse àtakò àláfíà sí ilé ìjoba Makurdi lóòní láti jé kí ìjoba gbárùkù láti jé kí won f’owó sí owó ntanràn jíjeko (Anti grazing bill) sínú òfin àti láti fajúro sí orísirísi  àbùkù /òròìwòye ti àwon Miyetti Allah Cattle Breader’s Association (MACBAN) ,wón tún pa àwon àgbè oníresì tí kò mo nkankan lára ní ìsodá bírìjì ilé-ìfowópamó, Àríwá (north bank).
Nígbà tí won ń gbin ìresì lówó ni àwon darandaran sí wo inú oko won tí àwon Eran won sì ń je oko won. Èsì ni è ń wò ní ìsàlè yìí bí won se gbé àwon àgbè tí ó se l’ése lo  sí ilé-ìwòsàn ifáfitì ìjoba ìpínlè Benue (Benue state university Teaching Hospital).Àwon ènìyàn wònyí (fúlàní) tún fi ara won hàn bí ó tilè jé wípé òfin ti báwa bu owó lù ú ìwé ntanràn jekojeko Anti grazing bill. Àwon fúlàní darandaran tún ń da àwon ònilè àti àwon tí ó ń fé àláfíà àwon ènìyàn ìjoba ìpínlè Benue láànú….

Continue after the page break for the English translation.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...