Home / Àṣà Oòduà / Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..

Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..

Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba Zakzaky àti Palestine kalè (papàájùlo lówó ìkolù àwon Israel

English Translation!
Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára