Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.
Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà Egbìnrìn ọ̀tẹ̀, bá a se n pàkan, nìkan ń rúÀwọ́n ọmọ ẹgbẹ́ “Islamic Movement of Naigeria” (IMN) tí gbogbo ènìyàn mọ sí Shi’ites lọ́jọ́ ajé ti ya sí ìgboro lágbègbè ilé ìtajà Bannex ni Wuse nílú Abuja láti wọ́de nítorí Olórí ọmọ ogun Iran Quasm Soleimani ti àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Amẹ́ríkà pa lọ́jọ́ Ẹtì tó kọjá. Bákan náà ni wọ́n pè fún ìtúsilẹ̀ adarí wọ́n Sheikh Ibraheem El-Zakzeky àti ìyàwó rẹ̀ ...